Don't wanna be here? Send us removal request.
Text
ÌTÀN DI ÒWE
........ITAN LO D'OWE.......... OWE:: '''Didun lodun ta nbọrẹ jẹkọ,tile oge toge jẹ''' Ni ilu sosogiriso,awon ọrẹ meji kan wa,ikan njẹ ADUNNI, ikeji a si maa jẹ OGE (oge ni anpe ọmọbinrin toba rẹw laye atijọ,ẹwa ni a npe won laye ode oni). Awon ọrẹ mejeeji yi fẹran ara won pupọ,debipw ọrẹ korikosun ni won jo nse,iya Adunni nta Ẹkọ bẹẹ iya Oge nta Ọlẹ,leyi to jẹ ki ọrẹ won tun fidimulẹ ju ti awon ẹlẹgbẹ won lọ,nitoripe won jọ maa nkiri ọja papọ ni. Kamọfọrọgun,lọjọ kan ni Oge gbera o dile ọrẹ rẹ,boti de ibẹ ni ọba ọrẹ rẹ lori ẹni to nfi ẹkọ san ẹfọ sọkọ,Oge o se meni se meji,lo un naa ba fikalẹ si lawon mejeeji ba jọ njẹun papọ. Bi won ti njẹun tan ni iya Adunni bọsita o si ri awon mejeeji,se o kuku mope isu ki sẹgbẹ iyan kuku ki sẹgbẹ agbado, ọlẹ rodo kuro loun ta nmoju si lawujọ oun jijẹ inu elewe,eyi lomu iya Adunni sọrọ lọjọ naa pe DIDUN LODUN TA NBỌRẸ JẸKỌ,TILE OGE TOGE JẸ........Yooba Dun!
0 notes